Thursday , July 18 2024

Aden Solomon – Tewogbope Lyrics

Welcome to our Music & Lyrics section. You are reading Aden Solomon – Tewogbope Lyrics. Download the audio by clicking the download button at the bottom of this page. Be blessed as you sing along.

Aden Solomon – Tewogbope Lyrics

Verse 1:
Araye èmò mò bámi ki bàbá mi o
Ko ma si elòmíràn ti ó dàbí ìré o
Alágbádá iná, aláwotèlè oorùn
Gbòngbò ìdílé jesè ‘wólè moràba o
Arúgbó ojó, Mo mú ópé mi wá, téwógbopé e
Bàbá mi o, elébùru iké o, i give you all the glory Lord

Chorus:
Téwógbopé mi o bàbá
Téwógbopé mi o bàbá
Téwógbopé mi o bàbá
Edámi sí o oò, e gbémi lèké eè

Verse 2:
Mowá gbé igá ópé fún bàbá à mi o
Bàbá tí óunse obè ìdùnú lójojumo
Bàbá defend mi o, lojokojo
Kò mà si elòmíràn ti odà biìre o
When yawa burst, na my agbejórò
Ayò ni saa èmi òmo sorrow
Ìgbékelémi èyìn ni mò n follow
Mo fé kí áráyé gbó, pé èyìn ni kan ni mò nbo

Verse 3:
Akirisore ò, kò jé fi mí seré ò
Òta òle dámi duro
Bàbá n gbé mi sáré
Mo gbé igá o pé, Mo mú ópé mi wá
I dey follow baba go, everyday na tweet
Tì mba ní ki n káre oluwa; ení èji éta èrin
Tì mba ní ki n káre oluwa; ìle àsu ìle àmó o

Back to Chorus
Till fade!

DOWNLOAD MUSIC

Thank you for reading Aden Solomon – Tewogbope Lyrics. Check out more lyrics on our Music & Lyrics section.