Thursday , July 25 2024

Arabaribiti Lyrics

Arabaribiti, Aribirabata, Oluwa awon oluwa, Olorun awon Olorun, Olorun Agbalagba

Verse 1
My voice will praise you Lord in the morning
My soul, you will praise thy Lord
Nitoripe Oruko re baba, lo la na si ori okun
Agbara re baba lo so hannah di olomo
Arabaribiti, Oba to ta so mo

Chorus
Arabaribiti, oba to ni ki orun ko yo, to si yo
Arabaribiti, oba to ta so mo

Verse 2
Instrumentalist
You are the Lord, you sitted upon thy throne
You are the King of Heaven and the Earth, Oluwa
Arabaribiti, oba to ta so mo

Repeat chorus

Ad-lips
Kabiesi ooooo,
Olutunu, olufe okan mi ni
Gbanigbani lo jo isoro
Owi be se be, agbanilagbatan
Oba ti duro ti ni
Metalokan, okan lana, okan loni, okan titi aiyeraye
Olorun baba, olorun omo, olorun emi mimo
Mimo mimo ni oruko re
Awon agba gba merinlelogun o
Aon ke mimo mimo si oruko re baba
Iwo lo ta so mo bi eni ta so, gbogbo idile jese
Ope lo fi ro ri, iyin lo fi ro eyin
Oba mi olowo gbogboro
Arabaribiti
My voice will praise you Lord in the morning
My soul, you will praise thy Lord

Download song here

DOWNLOAD MUSIC