Wednesday , May 22 2024

Badejo Jeremiah – Eledumare Lyrics

Eledumare Eledumare, imole to kari aye o
Eledumare Eledumare, awole agbosuba fun o
Oooo, oooo, oooo, oo, oooo

Jesu de okunkun a parada
Amo roro, ala roro, ala funfun yoo, amo funfun lao
Ogbenu wundia sola, ogbenu omo eniyan fohun, ogbenu adelebo sogo
Oba ti an sa ya, oba aidigbolu, eni digbolu o a si run womu o
Kukute nla nio tio mira jigi, eni mi kukute ara re lomi
Oloruko nla, oloruko to mu j’ogun abenu gongo
Alagbara nla to fayeraye agbara sagbara titi ayeraye o
Aki ki o tan, ao le yin o tan, eni mimo isreli
Ato pojo iku da, ato peri Eledumare
Mimo mimo arogo sogo, mimo mimo
Olojo lo korin kese
Awole agbosuba fun o

Back to chorus

Download song here

DOWNLOAD MUSIC