Saturday , July 20 2024

Bankie – Iwo l’Oba Lyrics

Solo 1
Iwo lo wa k’emi le joba, k’emi le d’ade, kemi le l’aiye
Iwo l’abi lati gba mi, lati fa mi s’inu imole
Iwo l’aabi taa koda, lati wa gba wa, Iwo l’Oba, Iwo l’Oba

Chorus:
Abi f’ese re, f’ese mi, f’ese wa
Abi k’a le ni iye aiyeraiye (Repeat)

Iwo l’o wa k’awa le j’oba, k’awa le d’ade, k’awa le l’aiye
Iwo l’abi lati gba wa, lati fa wa s’inu imole
Iwo t’aabi taa koda, lati wa gba wa, Iwo l’Oba, Iwo l’Oba
Iwo lo wa l’ati f’erin l’ati f’orin ayo s’aiye mi,
Iwo l’emi yoo maa sin l’emi yoo ma yin Olorun Orun
Iwo l’abi lati gba mi, lati wa fa mi s’inu imole
Iwo taabi taa ko da, lati wa gba wa, Iwo l’Oba, iwo l’Oluwa

Chorus:
Abi f’ese re, f’ese mi, f’ese wa
Abi k’a le ni iye aiyeraiye (Repeat)

Interlude

Bridge:
Dide ki o k’orin Ife Olorun, Ogo f’olorun l’oke orun
Awon angeli n’korin, awa eda aye ngberin
A wa pelu ebun iyebiye, pelu orin iyin ti ko n’iye
A f’ope fun Olorun wa, fun ‘fe nla to f’ife wa
E mu ade oba re wa, ogo f’oba t’abi.

Chorus till fade

Download song here

DOWNLOAD MUSIC