Tuesday , November 5 2024

Kenny K’Ore – Emi ni tie Lyrics

Tongues
Eyin oju BABA ni emi ooo

Ore ofe die si
Agbara die si
Aanu yin die si

Ore ofe die si
Agbara die si ooo
Aanu yin die si

Gbogbo aye mi
Ni maa fiyin O ooo
Gbogbo agbara…baba
Ni maa fiyin O ooo
Gbogbo emi mi
Ni maa fiyin O ooo

IWO ni temi…BABA
Em mi ti Re
Ooo (Slur)
IWO ni temi…ooo
Emi ni ti Re
Yeah (Slur)
Emi ni ti Re

Ore ofe die si
Agbara die si
Aanu yin die si

Ore ofe die si…BABA
Agbara die si ooo
Aanu YIN die si

Gbogbo aye mi
Ni maa fiyin O ooo
Gbogbo agbara…BABA
Ni maa fiyin O ooo
Gbogbo emi mi
Ni maa fiyin O ooo

IWO ni temi…ooo
Emi ni ti Re…ELEDUMARE gbo ooo
IWO ni temi…ooo
Emi ni ti Re

Yeah
Emi ni ti Re
IWO ni temi
Emi ni ti Re
Emi ni ti Re
Emi ni ti Re (x8)

Emi ni ti Re…ELEDUMARE gbo ooo
Emi ni ti Re…ELEDUMARE gbo ooo

Emi ni ti Re
Emi ni ti Re
ELEDUMARE gbo ooo
Emi ni ti Re

Download song here

DOWNLOAD MUSIC