Saturday , December 21 2024

Kent Oxygen, Oluwakemi – Ayo Mi Lyrics

Welcome to Acken Blog Gospel Music Lyrics section.

You are viewing Kent Oxygen, Oluwakemi – Ayo Mi Lyrics. Download the audio by clicking the download button at the bottom of this page.

Be blessed as you sing along.

Kent Oxygen, Oluwakemi – Ayo Mi Lyrics

Solo (Oluwakemi)
Tale bale torun wo
T’onikaluku re le won
Bo se mi nikan ngo yin o Olorun mi
Nigbakuugba
B’ojo ba mo t’orun ran
T’onikaluku sise won
Bo se mi nikan
Ngo yin o Olorun mi
Nigba gbogbo

Chorus (All)
Ayo mi la ‘to do re wa
Lo do re ni ireti san waa o
Ireti mi lat’odo re bo
Ire lo n ma ayo wa fun mi
Ma ma gbe o ga
Ibi isadi mo wole fun o
Ire l’apata igbala mi o
Idi re ti mo wa fi yin o
Olorun mi nigbakugba
Olorun mi Ele’eda mi Ade’e’da Aseda
Baba iwo l’ayo mi o
Iwo l’ayo mi o
Orisun ayo ti kii gbe ni o o
Titi aye
Titi ye ni ngo yin o o
Nigbati o wo ati igba ti o wo
Maa maa gbo kiki re
Olorun mi
Olorun mi ti bamise
B’omode ba royin ayo a s’akara ibanuje danu
Boti fun mi l’oyin ayo
Titi aye ni ngo yin o
Mo m’orin iyin senu mo gbe o ga
Titi aye ni ngo yin o o
Baba mi Olorun mi o
Iwo l’ayo mi o
Titi aye ni ngo yin o o
Ire ni iyin mi to si
Ire l’ola mi to si
Ire l’ope mi to si
Olorun mi ti bamise
Ohun t’aye ti ro pe ko se se nse lo se fun mi
Titi aye ni ngo yin o o
Afa yan ti ri ki lo se mi ti ngo wa ni maa yin o titi aye mi o
Titi aye ni ngo yin o o
Oh titi aye mi ah
Titi aye ni ngo yin o logo o

DOWNLOAD MUSIC

Thank you for viewing Kent Oxygen, Oluwakemi – Ayo Mi Lyrics. Check out more lyrics on our Gospel Music Lyrics section.