Wednesday , January 8 2025

Michael George – Oba Lyrics

Oun lo’Oba
Oba alese lewi Oba
Oun lo’Oba
Oba Oba to to Oba

Do you ever need a savior who will give you rest
More than a friend, He’s a father you can lean on when you go through test
He is the beauty of the world
The author of everything that’s good
Olore ofe, a to fara ti bi oke, Oba
Ma wi fa’ye, ma je kan mo, pe oba nla le je

Eho iho ayo, Jesu, oun l’oba gbogbo aye
Ko s’ala kawe, ko s’ala fiwe olorun mi, Oba anu
He is the beauty of the world
The author of everything that’s good
Olore ofe, a to fara ti bi oke o Oba
Ma wi fa’ye, ma je kan mo, pe oba nla le je

Eyin lo’Oba
Oba alese lewi Oba
Eyin lo’Oba
Oba Oba to to Oba

DOWNLOAD MUSIC