Wednesday , January 22 2025

Sola Allyson – Ijoba a Re De Lyrics

Welcome to Acken Blog Gospel Music Lyrics section.

You are viewing Sola Allyson – Ijoba a Re De Lyrics. Download the audio by clicking the download button at the bottom of this page.

Be blessed as you sing along.

Sola Allyson – Ijoba a Re De Lyrics

Ijoba re de
Ase re bere
Ijoba re de
Ase re bere
Agbara wa
O ba s’ori i mi
(7 times)

Ad lib:
Ijoba ola
Ijoba agbara oo
Ijoba alaafia
Ijoba re de oo
Ijoba ola
Ijoba agbara oo
Ijoba alaafia
Ijoba iserere

My men shall not be few
Agbara lat’odo re e wa
Bi mo ti n sa’pa mi
Lati wa ninu ife re
Ijoba re de
Ijoba aseyori
Ijoba riri iranwo ni temi
Ijoba re de o
Ase re bere
Agbara wa
O gbe mi wo bi ewu
O ro mi bi aso
O ba s’ori i mi

Bee naa ni oro re l’oso bee
Mo gbekele oro baba
Omo baba l’emi
Ijoba ola
Ijoba agbara
Ijoba alaafia
My men shall not be few mo so

Okunkun ka
Imole de
Iranwo de
Gbogbo ise n kun mi l’owo

Okunkun ka
Imole de
Iranwo de
Gbogbo ise n kun mi l’owo

Ise mo wa se
Ise imole maa s’aseye o
Maa rin arinto
(arinto ni t’emi l’ona mi)
Maa rin arinye
Agbara wa
O ba s’ori mi

Adlib
Okunkun ka!
Imole lati’ibi ti imole ti ntan
Iranwo de s’ori iseda mi
O tan s’ori iseda mi o
Okunkun ka ooo
Bee naa ni, bee naa ni
Maa rin arinto
Maa l’ajo ja
Maa rin arinto

Mo f’ebun sola
Bee naa l’ori
Mo f’ebun mi
F’ogo fun Oluwa
T’o le’ebun mi
Bee naa l’o ri
Ijoba re de
Owo yida l’ori iseda a mi
Ase re lat’orun bere bee naa ni
Owo yida l’ori iseda a mi
Isodotun de ba mi n’irin ajo mi
Bee na l’ori
My men shall not be few
Iranwo lat’origun mereerin agbaye temi ni
Bee na l’ori
Awon t’o maa gbe mi t’on maa sugba ohun
Mo gbe ka’ri won wa s’ona mi
Bee naa l’o ri
Ijoba re de o
Owo yida l’ori iseda a mi
Si ti aanu si ti iranwo
Si ti iserere bee na ni
Owo yida l’ori iseda a mi
Iranwo ti mi o ri ri
Maa rii l’ona gbogbo
Bee naa ni
Aye e mi a bu ola fun o
Enit’oni ebun mi
Bee naa ni
Bee naa l’ori
Bee naa l’ori o pelu ase baba a mi
Owo yida l’ori iseda a mi
Mo ti di omo (3x)
Apere omo han l’ara a mi
Owo yida l’ori iseda a mi

Agbara wa
O ba s’ori i mi
Agbara wa
O ba s’ori i mi

DOWNLOAD MUSIC

Thank you for viewing Sola Allyson – Ijoba a Re De Lyrics. Check out more lyrics on our Gospel Music Lyrics section.