Friday , December 27 2024

Aramide – Oba wa de Lyrics

Welcome to our Music & Lyrics section. You are reading Aramide – Oba wa de Lyrics. Download the audio by clicking the download button at the bottom of this page. Be blessed as you sing along.

Aramide – Oba wa de Lyrics

Ha – lle – lu u yah
Oba wa de, Oba wa ( Our King is born)
O O de , Oba wa
Abi si ibuje eran
O O de lati da wa lare
E e e e

Chorus:
Call: Ayo baye aye eyo oba wa de
Resp: Oba wa, Oba wa, Eyo Oba wa de Oba wa
Call: Itura de aye eyo Oba wa de
Resp: Oba wa, Oba wa, Eyo Oba wa de Oba wa
Call: Ko siku mo, aye eyo Oba wa de
Resp: Oba wa, Oba wa, Eyo Oba wa de Oba wa
Call: Lati gba wa kuro ninu ese wa gbogbo
Resp: Oba wa, Oba wa, Eyo Oba wa de Oba wa
Call: Oti dee
Resp: Oba wa de, Itura dee
Olugbala dee, abi Jesu fun wa ah ah
Emmanueli lao ma pe oruko Re
Ogo f’Oba ta bi saye
(Repeat chorus again)

Solo: Bawon Oluso aguntan tin so eran ( Ti nso eran)
Angeli Oluwa sokale to won wa
O so fun won nipa Olugbala ti a bi (Ti abi)
Ogo ogo f’Olorun ni orin ti won nke
Ife inu rere Re si eniyan

Chrs:
Call: Ayo baye aye eyo oba wa de
Resp: Oba wa, Oba wa, Eyo Oba wa de Oba wa
Call: Itura de aye eyo Oba wa de (Kabo O)
Resp: Oba wa, Oba wa, Eyo Oba wa de Oba wa
Call: Ko siku mo, aye eyo Oba wa de
Resp: Oba wa, Oba wa, Eyo Oba wa de Oba wa
Call: Lati gba wa kuro ninu ese wa gbogbo
Resp: Oba wa, Oba wa, Eyo Oba wa de Oba wa
Call: Oti dee
Resp: Oba wa de, Itura dee
Olugbala dee, abi Jesu fun wa ah ah
Emmanueli lao ma pe oruko Re
Ogo f’Oba ta bi saye

 

Solo: Ogo f’Oba ta bi saye
Resp: Ogo f’Oba ta bi saye
Solo: Ope, iyin ogo ni f’Oba ta bi saye
Resp: Ogo f’Oba ta bi saye
Call: Oba ta bi fun wa
Resp: Abi
Call: Abi k’eniyan mase ku
Resp: Abi
Call: Abi k’O le rawa pada
Resp: Abi
Call: Abi k’Ole tun wa bi
Resp: Abi
Call: Ka le niye ayeraye
Resp: Abi
Call: Iyin ogo ni f’Oba ta bi saye
Resp: Ogo f’Oba ta bi saye
Call: Emmanueli lao ma pe oruko Re
Resp: Ogo f’Oba ta bi saye
Call: Emmanueli lao ma pe oruko Re
Resp: Ogo f’Oba ta bi saye

Call: Ibii Jesu lo so mi domo
Resp: Ibii Jesu lo so mi domo
Solo (Ewi) : Ka bi e si o
Oba ta bi, ti a ko da
To wa saye, to loyun ara Re
To bi ‘ra Re, to si tun so ‘ra Re loruko
Iyanu, Oludamoran, Olorun Alagbara
Oba Ayeraye, Omo Alade Alafia
Oun naa tun lakoda aye
Onise nla ti nsohun tenikan oleseee

Call: Ibii Jesu lo so mi domo
Resp: Ibii Jesu lo so mi domo
Call: Ibii Jesu lo so mi domo
Resp: Ibii Jesu lo so mi domo
Call: Lo so mi domo
Resp: Lo so mi domo
Call: Sohun lo so e domo
Resp: Lo so mi domo
Call: Oun lo so wa domo
Resp: Lo so mi domo
Call: Omo ni wa, a kii seru
Resp: Lo so mi domo

Call: Ani, Ibii Jesu lo so mi domo
Resp: Ibii Jesu lo so mi domo
Call: Ibii Jesu lo so mi domo
Resp: Ibii Jesu lo so mi domo
Call: Ibii Jesu lo so mi domo
Resp: Ibii Jesu lo so mi domo

 

 

 

 

 

 

DOWNLOAD MUSIC

Thank you for reading Aramide – Oba wa de Lyrics. Check out more lyrics on our Music & Lyrics section.