Thursday , January 23 2025

Added on : Oct 22, 2014 – Orun Oun Aye – Tope Alabi Lyrics

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

Didara orun oun so togo Re o Olorun
Ewa Re to yi aye ka n so togo Re bo ti po to
Gbogbo eda eranko at’ewebe n yin O o
Ise owo Re gbogbo lo n keyin le, won yin O o Baba

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

Ola lo wo laso, ogo lo fi pa kada orun
Ika ese Re o n han l’ori apata
Esin Re n fogo yan l’ori awo okun o Olola nla
Kini o waa se mi ti n o jokeleyo
Ti n o ni le juba Re Oba

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

Gbogbo eemi inu mi o n yin O yato Olorun mi
Iwo to mu la ina koja to fi mumi goke
Kini mba fi fun O
Kini mo tosi ninu Oreofe ti mo rigba lodo Re
Oba ye mida majemu lati nu’mole
Oro ye ye osise
Oba ti ki n dale oro Ore
Iwariri ni n o fi juba Re

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

Orun oun aye kun fun ogo Re
Orun oun aye kun fun ogo Re
Egbegberun awon irawo kede ogo Re
Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e

DOWNLOAD MUSIC