Saturday , December 21 2024

King BunmiGold – Ologo julo Lyrics

Welcome to Acken Blog Gospel Music Lyrics section.

You are viewing King BunmiGold – Ologo julo Lyrics. Download the audio by clicking the download button at the bottom of this page.

Be blessed as you sing along.

King BunmiGold – Ologo julo Lyrics

INTERLUDE

Lead
Ologo julo
Alanu julo
Eyin ni Oluwa
Awimayehun

Back
Ologo julo
Alanu julo
Eyin ni Oluwa
Awimayehun

STRING SOLO…

VERSE1
Talo dabi ire, Olorun tologo
Alanu leje e, olutunu aye wa
Gbanigbani leje, Oba togbawa lowo aye
Opomulero ni o, olorun alanu
Ninu orun lohun gbe, Imole lofi nso go re o
Eyin ni Oluwa, Awima yehun

CHORUS:
Ologo julo
Alanu julo
Eyin ni Oluwa
Awimayehun(2ce)

VERSE 2:
Oda ye, ninu ogo re ni
Oda orun, ninu ola re ni
Kabi e si, Oba tologo
Agbara re po o, Olorun ni o
Ninu orun lohun gbe, Imole lofi nsogo re o
Eyin ni Oluwa, Awimayehun.

CHORUS:
Ologo julo
Alanu julo
Eyin ni Oluwa
Awimayehun(2ce)

DOWNLOAD MUSIC

Thank you for viewing King BunmiGold – Ologo julo Lyrics. Check out more lyrics on our Gospel Music Lyrics section.